There is a single Creative Force (Òlódùmarè)
On this, Odu Ifa Okanran Ọwọnrin says:
The one whose influence spreads around the world
The one whose presence flows through every land
The one who spreads the mat perpetually
Ifa’s message to Òlódùmarè Agotun...
My God is unique.
It is called Òlódùmarè.
The universes forces are many.
They are called Òrìşà and Irunmolè.
Òsá Aláwòo says:
Òsá Aláwòo n Ikin ni nje Òtító?
Mo ni Kinni nje Òtító.
Ni Oluwo Ợrùn tii daabo bo ile Aye
Ọrúnmìlà ni Òtító ni emi airi tii daabo ile aye
Òun ni Ogbon ti Òlódùmarè nlo
Òsá Aláwòo ni kinni nje Òtító?
Mo ni Kinni nje Òtító?
Ọrúnmìlà ni Òtító ni ìwà Òlódùmarè
Òtító ni oro ti kii ye
Ifá ni Òtító
Òtító ni agbara to ju gbogbo agbara lo
Ire aye ràyè
Díá fun Ile Aye won ni ki won maa s’otito
S’otito s’ododo Eni ba s’otito ni mole ngbe.
Aboru, Aboye Áwo
-Ary Carvalho .
Source: FB
No comments:
Post a Comment